Awọn ọmọ-ọmọ Japanese ni Brazil sọ ni èdè Japanese
Mo ri eto kan lori Telifisonu lalẹ. Ninu eto yi awọn ọmọ-ọmọ Japanese ni Ìlú Brazil n sọrọ ni èdè Japanese. Kilode ti awọn ọmọ-ọmọ Ànàgó ti o wa ni Bahia kò sọ èdè Yorùbá Ànàgó rara ni aye ojoojumọ? Kilode ti a ko sọ awọn oriṣiriṣi ede abinibii ni awọn agbegbe awa? Ó se pàtàkì láti mọ díẹ̀ nípa ìtàn ilẹ̀ Ànàgó àti irú ènìyàn tí ń gbé awọn ìlú Ànàgó kaakiri agbaye . Nigbati àwọn Òṣèlú gba Ìjọba lọ́wọ́ Ìjọba Ológun, inú ará ilú dùn nitori wọn rò wi pé Ológun kò kọ iṣẹ́ Òṣèlú. Sibẹsibẹ, ko si ohun ti o yipada fun awọn ọmọ-ọmọ eniyan Afrika ni orile-ede awa.. Tradução Os descendentes de Japoneses no Brasil falam Japonês Eu vi um programa na televisão hoje à noite. Neste programa, as crianças japonesas no Brasil falavam japonês. Por que as crianças descendentes do povo nagô da Bahia não falam a língua iorubá-nagô na vida cotidiana? Por que não falamos as respectivas línguas africanas diferentes em nossas áreas? É importante sabe...