Èṣù jẹ́ Òrìṣà ti àwọn Nàgó ń bọ ni Ọjọ́ Aje.


ku dede iwoyii o,

´álàáfíà l´?

Orúkọ tèmi ni Ọ̀jọgbọ́n Adelson de Brito ti gbogbo yin mọ̀ si Mawo Adelson.

Ki ni ọjọ́ ni oni?

Oni ni Ọjọ́ Aje.

Ni Ọjọ́ Aje, lìlú awa, àwọn Nàgó ń b Òrìà meji:

1.    wọn ń bọ Òrìà Èu

2.    (ati) wọn tún ń bọ Òrìà Ṣọ̀npọ̀nnọ́ ti a ń pe Òrìà Obaluwaye tabi Òrìà mlú.

Lóní, Mo yóò sọ̀rọ̀ nipa Òrìà Èù.

jẹ́ ki a ki Èù ni akọ́k aaju ki a sọ̀rọ̀ nipa oun....

“Kò gba,

Laroye, Èù!

Èù Mojúbà.

Ẹlẹgbára ajágbn wò si

Araketu ń sọ̀rọ̀ ń sọ̀rọ̀.

Èù jìnnìjìnni 

Kò gba,

Laroye! ”

Òrìà ti ẹ̀dá ati ọ̀rọ̀, Èù lagbára jù nínú gbógbó ìránṣẹ́ Ọlọ́run l.

Ìtan sọ fún wa pe Èṣù jẹ́ ẹ̀dá kan pàtàkì ti Ọlọ́run fẹran pupọ̀.

Ó ni Òrìṣà òjíṣẹ́ laarin gbogbo Òrìṣà ati Ọlọ́run.

Bẹ́ẹ̀ni, ó tún òjíẹ́ laarin àwọn Òrìṣà ati ènìyàn.

Èù alábapin ninu iṣẹda ti agbaye ati funrararẹ lò ń e.

Ilẹ̀ Oun ni àwọn ọ̀na òpópó agbaye, ti o ni idi ti o tún mọ si “Òrìṣà ìta”.

Ó máa nrin kaakiri ni pẹlu Agongo Ọ̀gọ rẹ̀, ṣe afihan ó lagbára ti ẹ̀dá, ṣe igbesi aye gbangba.


Ó tún olùtọ́jú ti àwọn ilé Òrìṣà, àwọn ilé ènìyàn, àwọn ìlú ati àwọn ènìyàn ti n gbé loju òpópóna.

Ìta gbangba l´a ngbe ère rẹ̀ si, a kò gbọd ri i mọ̀´lẹ̀ si´nu yara. Idi niyi ti àwn Yoruba fi i s pé “Èù kò ni iwà, a kọ́ ilé rẹ̀ sí ìta”.

Kò si ohunkan ninu agbaye pátápátá ti o le ṣe ti Èù kò ba gba.

Fún idi eyi, àwọn onigbagbọ sin Èṣù ni àkọ́kọ, ṣaaju ki wọn n sin Òrìṣà miiran.

Èṣù jẹ́ òrìsà kan pàtàkì ti a ńsin jákèjádò ilẹ̀ Yorùbá.

Ìlú Bahia jẹ́ nkan pàtàkì ti ilẹ̀ Yorùbá kuro ni Afirika, eyiti a fi idi múlẹ̀ bí Olù-ìlú Yourùbá ti gbogbo Amẹ́rikà nipasẹ Ọọ̀ni Ilè-Ifẹ̀ náà, Ọba Adeyeye Babatunde Enitan Ogunwusi, Ojaja II (keji), ni Oṣu Kẹfà ọjọ́ 10 (mewa) ọdun 2018.

Tradução

Exu, Orixá que os Nagô cultuam na segunda-feira

Saudações

Tudo em a paz com vocês?

Meu nome é Professor Adelson de Brito, mais conhecido como Mawo Adelson.

Que dia é hoje?

Hoje é Segunda-feira.

Na segunda-feira, em nossa cidade, o povo Nagô adora duas divindades: adoramos Exu e adoramos Xapanã que chamamos Obaluayê ou Omolu.

Hoje, vou falar sobre Exu.

Vamos cumprimentar Exu antes de falarmos sobre ele ....

Essa saudação não será traduzida aqui

Divindade da Criação e da Comunicação, Exu é o mais forte entre todos os servos de Deus.

A história nos diz que o Exu é uma Criatura muito importante para Deus.

Ele é o Mensageiro entre todas as divindades e Deus.

Sim, ele também é o Mensageiro entre as Divindades e o homem.

Exu está envolvido na criação do mundo e de si mesmo.

Ele é dono das estradas do mundo, por isso também é conhecido como a "divindade de fora".

Ele anda por aí com seu bastão em forma de falo, exibindo suas habilidades de Criador, fazendo aparições públicas.

Por esta razão, os adeptos adoram Exu primeiro, antes de adorar qualquer outra divindade.

Exu é uma das divindades mais importantes veneradas em toda a terra ioruba.

A cidade da Bahia é uma importante terra Iorubá, que foi instituída como Capital Iorubá das Américas, pelo Ooni de Ilê-Ifé, or Sua Majestade o Rei Adeyeye Babatunde Enitan Ogunwusi, Ojaja II (II), o Ooni de Ilé-Ifé, no dia 10 de junho (dez) 2018.

Referencias:

1.    DARAMLA, O. ati JEJE, A.; Awn Àà ati Òrìà Ilẹ̀ Yoruba; Ibadan Press, Nigeria, 1975.

2.    BRITO, Mawo Adelson; EXU: Èù lgbara é Vodun Legba; Salvador, Bahia; Press Color; 2018.

3.    Imagem: https://br.pinterest.com/pin/29414203796712333/ (acessado em 10/08/20)

 

 


Comentários

Postagens mais visitadas deste blog

O Clã Nagô-Vodun Sakpata-Azansù

A Primeira Cartilha de Liturgia Jeje Savalu do Candomblé da Bahia

A Liturgia Vodun e o Candomblé Jeje da Bahia