Ni Olú-ìlú ipinlẹ̀ Bahia àwọn aláwọ̀ dúdú lò èdè Nàgó




ku dede iwoyii o,
e àlàáfiíà ni?
Ara ile n kọ́?
Iṣẹ́ n kọ́?
Orúkọ temi ni Olukọ́ Adelson de Brito, ti gbogbo yin mọ si Mawo Adelson.
Emi ni olukọ́ èdè Yorùbá-Nàgó (tabi Èdè Nàgó) ni Ìlú Salvador, ti Olú-ìlú Ipinlẹ̀ Bahia ló ń é.
Mo si tún jẹ́ Olori Ẹ̀sin ibilẹ̀ Òrìṣà.
e o mọ̀ wípè ni ibẹ̀rẹ̀ ọ̀rùndún mọ̀kandilogun (século XIX), ọ̀pọlọ́pọ̀ aláwọ̀ dúdú ti gbé ni Ilu Salvador nitori òwò ẹrú ?
Bẹ́ẹ̀ni, ni ìgbà òwò àwọn ènìyàn dúdú wọnyi kúrò ni oriṣiriṣi agbegbe kaakiri gbogbo ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú labẹ̀ agbára àwn oyinbo.
Nigba ti àwọn ọm ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú yìí wa de ni oriẹ̀-èdè Brasili wọn kò le lò èdè Pọtugi rara.
Amọ́n, àwọn ènìyàn Nàgó mọ̀ nipa ètó ṣiṣẹ pọ̀ nigba to wn gbe ni ilẹ̀ Afirika, aaju ti òwò ẹrú
Nitorinaa, èdè wọn di èdè ti wópọ̀ ibaraẹnisọ̀rọ̀ laarin ara àwọn ọm aláwọ̀ dúdú ti n gbe ni ìlú Salvador laibikita ti ẹ̀yà abinibi wn.
Ni ode oni ni ibi gbogbo agbaye èdè Nàgó ti gbogbo yin mọ si èdè Yorùbá.
Mo dúpẹ́ lọwọ́ gbogbo olólùfẹ́ èdè Yorùbá, pataki àwọn ti o fi ìfẹ́ tẹ̀ lé àkọ-sílẹ̀ ọ̀rọ̀ gbígbé èdè àti àṣà Yorùbá́ lárugẹ lóri ẹ̀rọ ayélujára.
Èdè ati àà Yorùbá-Nàgó ń gbooro si agbaye.
Ẹ jẹ ki a gbé èdè àti àṣà Yorùbá Lárugẹ.

Tradução

Na capital do estado da Bahia, os negros falavam a língua Nagô

Tudo bem?
Tudo em Paz?
A família vai bem?
E o trabalho?
Meu nome é Professor Adelson de Brito, mais conhecido como Mawo Adelson.
Sou professor de língua Iorubá-Nagô (ou Nagô) em Salvador, capital do estado da Bahia.
Eu também sou o sacerdote da religião tradicional Orixá.
Você sabia que no início do século XIX, muitos negros viviam em Salvador por causa da escravidão?
Sim, na época da escravidão, esses negros deixaram diferentes partes do continente africano negra por força da escravidão dominada pelos europeus.
Quando esses africanos chegaram a Brasil, não sabiam falar português.
O povo Nagô era muito organizado quando viviam na África antes do tráfico negreiro.
Como resultado, sua linguagem se tornou a linguagem de comunicação entre os negros que viviam em Salvador, independentemente de suas respectivas etnias.
Hoje, a língua Nagô é conhecida em todo o mundo como Iorubá.
Gostaria de agradecer a todos os amantes da língua Iorubá, especialmente aqueles que adotaram com carinho a promoção da língua e cultura Iorubá na internet, a língua e a cultura Iorubá-nagó estão se expandindo em todo o mundo.
Vamos promover a língua e a cultura iorubá.

Referencias:

1.    “Ilé làbọ̀ simi oko, ṣùgbọ́n bi ilé bá sanni àwọ̀ là nwò”: “Home is for rest on return from the farm, but the convenience of the home is a reflection on the skin”

(acessado em 25/07/20).

Comentários

Postagens mais visitadas deste blog

O Clã Nagô-Vodun Sakpata-Azansù

A Primeira Cartilha de Liturgia Jeje Savalu do Candomblé da Bahia

A Liturgia Vodun e o Candomblé Jeje da Bahia