Èṣù jẹ́ Òrìṣà ti àwọn Nàgó ń bọ ni Ọjọ́ Aje.
Ẹ ku dede iwoyii o, Ṣ ´álàáfíà l´ ẹ wà ? Orúk ọ tèmi ni Ọ̀ j ọgbọ́ n Adelson de Brito ti gbogbo yin m ọ̀ si Mawo Adelson. Ki ni ọj ọ́ ni oni? Oni ni Ọjọ́ Aje . Ni Ọjọ́ Aje , lìlú awa , àwọn Nàgó ń b ọ Òrì ṣ à meji: 1. w ọn ń bọ Òrì ṣ à È ṣ u 2. (ati) w ọn t ún ń bọ Òrì ṣ à Ṣọ̀ np ọ̀ nn ọ́ ti a ń pe Òrì ṣ à Obaluwaye t abi Òrì ṣ à Ọ m ọ lú. Lóní, Mo yóò s ọ̀ r ọ̀ nipa Òrì ṣ à È ṣ ù. Ẹ j ẹ́ ki a ki È ṣ ù ni ak ọ́ k ọ ṣ aaju ki a s ọ̀ r ọ̀ nipa oun.... “Kò gba, Laroye, È ṣ ù! È ṣ ù Mojúbà. Ẹl ẹgb ára ajágb ọ n wò si Araketu ń sọ̀rọ̀ ń sọ̀rọ̀ . È ṣ ù jìnnìjìnni Kò gba, Laroye! ” Òrì ṣ à ti ẹ̀ dá ati ọ̀ r ọ̀ , È ṣ ù lagb á ra j ù nínú gbógbó ìránṣẹ́ Ọl ọ́ run l ọ . Ì tan sọ f ú n wa pe Èṣù j ẹ́ ẹ̀dá kan pàtàkì ti Ọlọ́run fẹran pupọ̀. Ó ni Òrìṣà òjíṣẹ́ laarin gbogbo Òrìṣà ati Ọlọ́run. Bẹ́ẹ̀ni, ó tún òjí ṣ ẹ...