A língua do Nêgo Nagô
Tiriri, tiriri, tiriri Ô, é a
língua do ‘Nêgo Nagô,
Tiriri, tiriri, tiriri Ô, é a língua do ‘Nêgo
Nagô,
Tiriri, tiriri, tiriri Ô, é a língua do ‘Nêgo Nagô.
Ṣe o mọ̀ wípé, ní àkókò òwò ẹ̀rú ni ìlú Bahia, àwọn ènìyàn dúdú ti n gbé ni ìlú yìí kò le sọ èdè Pọtọgi?....
Bẹ́ẹ̀nani, ni ìgbà yẹn ni ílú Bahia ọ̀pọlọ́pọ̀ ènìyàn dúdú ti a mú wá lati oríṣiríṣi agbegbe ti ilẹ̀ Afirika, lò oríṣiríṣi èdè ti wọn fún àwọn ohun aye ojoojumọ́ wọn...
Laarin àwọn ọmọ dúdú tí a mú wá lati agbegbe ti iwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Afirika,
àwọn Fon, àwọn Aṣanti,
àwọn Fanti, àwọn Mina,
abi gbogbo àwọn ti a
pè “Jeje” lò olúkúlùkù èdè ti ara wọn.
Ṣùgbọ́n, àwọn Ketu,
àwọn Egba, àwọn Egbado,
àwọn Sabe abi gbogbo àwọn ti a
pè “Nàgó” lò èdè kanna
ti gbogbo wọn ni ilẹ̀ Kàáàrọ̀-oó-jíire... wọn lò èdè ti a pè “Ànàgó” tabi “Nàgó”...
Èdè Nàgó
náà èdè ti a lò nisin ló ń ṣe.
Bẹ́ẹ̀ni, èdè Nàgó jẹ́ èdè kanna ti a pe “Yorùbá”
ni ode oni...
Ni
osu ti ń bọ Emi yóò kọ Àwọn
ẹ̀kọ́ èdè yorùbá fún alákọbẹ̀rè ni Gabinte Portugues de Leitura – GPL
A kò gbọdọ gbagbe pe ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá ló ń ṣe.
Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá.....
Orukọ temi ni Mawo
Adelson
Tiriri, tiriri, tiriri Ô, é a
língua do ‘Nêgo Nagô,
Tiriri, tiriri, tiriri Ô, é a língua do ‘Nêgo
Nagô,
Tiriri, tiriri, tiriri Ô, é a
língua do ‘Nêgo Nagô.
Tradução
Você sabia que, durante a escravidão na Bahia, os negros
que moravam nesta cidade não sabiam falar português? ....
Sim, naquela época na cidade da Bahia, muitos negros de
diferentes partes da África usavam idiomas diferentes para o seu dia a dia ...
Entre os negros trazidos da África Ocidental, os Fon, os
Ashanti, os Fanti, os Mina ou todos os chamados "Jeje" falavam cada
povo a sua própria língua.
No entanto, os Ketu, os Egba, os Egbado, os Save, ou seja, todos
aqueles referidos como "Nagô" usam a mesma língua da terra Kaaro Ojire... eles usam a língua
chamada "Ànagô" ou "Nagô" "...
Nagô é a língua que estou usando agora.
Sim, Nagô é a mesma língua que hoje se chama de Língua Iorubá...
No próximo mês, darei aulas de ioruba para iniciantes em Gabinete
Português de Leitura - GPL
Não devemos esquecer que a língua Iorubá é uma língua tonal.

Comentários
Postar um comentário