Postagens

Mostrando postagens de março, 2021

Ogbomoso quintuplets birth: Ìyàwó àgbẹ̀ bí ìbarùn-ún lẹ́yìn ọmọ márun-ùn ní Ogbomoso láì ṣe iṣẹ́ abẹ

Imagem
https://www.bbc.com/yoruba/56344114 (accessed on March 11, 2021) Ayọ abara tin-tin ni nile ọkunrin agbẹ kan ati iyawo rẹ, to bi ọmọ marun-un lẹẹkan ṣoṣo nilu Ogbomọsọ nipinlẹ Ọyọ. Dokita ileewosan Ayoka Clinic and Maternity Centre, Oke-Ado, Ogbomọṣọ, Dokita Afolabi Sikirulahi sọ fun BBC Yoruba pe fun'ra obinrin naa, Funmilayo Oluwadara, lo bi awọn ọmọ naa lai ṣe iṣẹ abẹ.  Ọjọ kẹrin, oṣu Kẹta, ọdun 2021 lo bi awọn ọmọ naa, ati pe laarin ọgbọn iṣẹju pere.  O ni alaafia ni iya ati awọn ọmọ naa wa.  Bakan naa ni dokita ṣalaye pe obinrin naa ti bi ọmọ marun-un tẹlẹ, eyi to mu ki apapọ ọmọ ti oun ati ọkọ rẹ ni jẹ mẹwaa. Obinrin mẹrin, ọkunrin kan ni awọn ibarun ti Arabinrin Oluwadara ṣẹṣẹ bi i. A gbọ pe ẹni ọdun mejidinlogoji ni obinrin naa, ti ọkọ rẹ to jẹ agbẹ lati orilẹ-ede Togo, Idowu Oluwadara si jẹ ẹni ogoji ọdun, n gbe ni abule Ahoroko nilu Oyo. Ọgbẹni Oluwadara sọ fun BBC pe niṣe ni ara oun dabi ẹni ti wọn da omi si lara, nigba ti wọn sọ fun oun pe ibarun ni iyawo oun b...

Minha fala Fon de hoje!

Imagem
  Fɔngbe ce xwele bi tɔn ! Nε mi f ɔ́n g b ɔn? Un nɔ nyi Adelson Un gosin Brésil   O que eu disse foi :   – Como vai você? – Eu me chamo Adelson – Sou do Brasil.   Eu falei as frases acima em língua Fon. As primeiras palavras escritas nesse texto compuseram a seguinte frase : Fɔngbe ce xwele bi tɔn ! ou seja “Minha língua Fon de hoje” O povo Fon, também chamado de Fon nu, Agadja ou Dahomey, é um grupo étnico Gbe. Os Fon formam o maior grupo étnico do Benin, e habitam principalmente a região sul; eles também são encontrados no sudoeste da Nigéria e Togo. Sua população total é estimada em cerca de 3.500.000 pessoas, e eles falam a língua Fon, uma das línguas da constelação linguistica Gbe . O Benin oficialmente a República do Benin anteriormente conhecido como Daomé) , é um país da África Ocidental. Faz fronteira com Togo a oeste, Nigéria a leste, Burkina Faso a noroeste e Níger a nordeste. A maioria de sua população vive no ...