Ìlú ti Bahia jẹ́ ìlú ti èyìàn dúdú pọ̀ jùlọ ni agbaye lẹ́hìn Afirika
Orúk ọ tèmi ni Olúk ọ agba Adelson de Brito ti gbogbo yin m ọ̀ si Mawo Adelson Emi ni Olùk ọ́ Èdè àti À ṣ à Yorùbá-Nàgó . Mo si tún j ẹ́ olori Ẹ̀ sin Ibil ẹ̀ Òrì ṣ à ati Vodun ní ìlú Salvador, ti olú-ìlú ipinlẹ̀ Bahia. O ti pe ẹ̀ ẹ́ d ẹ́gb ẹ̀ta ọdún bayii ti owo ẹrú ti bẹrẹ jakejado agbaye, tawọn oril ẹe de agbaye si ti se ọpọ eto lati se ayẹyẹ náà. Fún àp ẹẹrẹ, ni oşù keji ọdún ní orílẹ̀-èdè Amẹ́rika (USA) jẹ́ àsìkò ti wọn máa şe ìrántí ìtàn àwọn adúláwọ̀ ti o jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́rika. Brasili tíi ṣé orílẹ̀-èdè kéji ti àwọn aláwọ̀ dúdú pọ̀ sí jùlọ àgbáyé lẹ́hìn orilẹ̀-èdè Naijiria. Ni ode oni ni ìlú Brasili, ani bi ọgọ́ta millionu àwon ènìyàn dúdú toj ẹ́ ọmọ ọmọ àwọn ẹrú tẹ́lẹ̀ , ṣùgbọ́n, kosi ohun kankan ti i jọba maa şe fún ìrántí ìtàn àwọn adúláwọ̀ ti o jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè yìí. Salvador lok ọ́kọ́ jẹ́ Olú ìlú Brasili lati Ọdún 1549 titi di Ọ dún 1763, elekeji ni Ìlú Rio de Janeiro, lati Ọ dún 1763 titi di 1960, l ẹ́hìn igbana, Brasilia ...