Ni Olú-ìlú ipinlẹ̀ Bahia àwọn aláwọ̀ dúdú lò èdè Nàgó
Ẹ ku dede iwoyii o, Ṣ e àlàáfiíà ni? Ara ile n kọ́? Iṣẹ́ n kọ́? Orúkọ te mi ni Olukọ́ Adelson de Brito, ti gbogbo yin mọ si Mawo Adelson. Emi ni olukọ́ èdè Yorùbá-Nàgó (tabi Èdè Nàgó) ni Ìlú Salvador, ti Olú-ìlú Ipinl ẹ̀ Bahia ló ń ṣ é. Mo si t ún j ẹ́ Olori Ẹ̀sin ibil ẹ̀ Ò rìṣà . Ṣ e o m ọ̀ wípè ni ibẹ̀rẹ̀ ọ̀rùndún mọ̀kandilogun (século XIX), ọ̀pọlọ́pọ̀ aláwọ̀ dúdú ti gbé ni Ilu Salvador nitori òwò ẹrú ? B ẹ́ ẹ̀ ni, ni ìgbà òwò ẹ rú à wọn ènìyàn dúdú wọnyi kúrò ni oriṣiriṣi agbegbe kaakiri gbogbo ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú lab ẹ̀ agbára àw ọ n oyinbo. Nigba ti à wọ n ọm ọ il ẹ̀ aláw ọ̀ dúdú yìí wa de ni ori ẹ̀ -èdè Brasili wọn kò le lò èdè Pọtugi rara. Am ọ́ n, àwọn ènìyàn Nàgó mọ̀ nipa ètó ṣi ṣẹ pú pọ̀ n igba to w ọ n gbe ni i lẹ̀ Afirika, ṣ aaju ti òwò ẹr ú . Nitorinaa, èdè wọn di èdè ti wóp ọ̀ ibaraẹnis ọ̀ r ọ̀ laarin ara àwọn ọm ọ al áw ọ̀ dúdú ti n gbe ni ìlú Salvador laibikita ti e...